Linguistics-Scholarly Publications
Permanent URI for this collection
Browse
Browsing Linguistics-Scholarly Publications by Author "Ilori, J.F"
Now showing 1 - 1 of 1
Results Per Page
Sort Options
- ItemOpen AccessIhun Awon Iso Elerun-Un Ni Yoruba(2015) Ilori, J.FAlaye itupale ihun awon iso elerun-un ni, paapaa ehun [OR ni OR] (to wa ninu gbolohun bf Akin pa [mama ni eran), ati ise ti ni n se nibe ko tii niyanju ninu glrama Yoruba (Awobuluyl 1978, 2013; Oyelaran 1989; Bamgbose 1990). Beba yii pe akiyesi si awon eri tuntun kan nipa ehun semantiikl ati sintaasl awon iso naa eyi to fi ro arojare pe ete itenumo onni (possessor) yato si ini (possessum) inu ehun onibaatan to je ipile ti a ti seda iso elerun-un-ni onibaatan-ajemo-ini (possessive-genitive ni-expression) lo bi idaru aato inu ihun awon isoyen. Bakan naa lo tun gbe eri kale lati fi han pe wunren ni kan yii naa lo n jeyo ninu awori iso ti a ti maa n sope ni n sise oro-atokun to n toka ibi/ogangan-isele (location) ninu girama Yoruba.