Linguistics-Scholarly Publications
Permanent URI for this collection
Browse
Recent Submissions
Now showing 1 - 5 of 149
- ItemOpen AccessÌlò-Èdè Nínú Ìwé Ìtàn Àròsọ Ó LE KÚ(DB MARTOY BOOKS, IBADAN, 2016) Òjó, E. T.Opolopo awon onimb ede Yoruba Id ti sise Ion ede ati lid ede Yoruba* (Bamgbdse, 1974; Isola, 1978; Ola'tu'nji, 1984; Opa'dotun 2003; Ogunsina, 2009). Ede ni igi leyin ogba ise-ona kan. Ede ni 'iplle ise-ona. 8i ede ohkowe tabi anise-pna kan ba mehe, ise naa kd ni wuyi, kd ni je akagbadun. Ede je ona ati irin-ise 'iba'nisbro. Ede ni bpdmulerd ati emi litiresodfde ni o je epo ti i gbe oko litireso fin; dun si ni eje ti i fun litireso ni okun ati agba'ra lati mi..,Ede je ona 'ibanisoro ati ona lati gbe ero gkan ati Imblara eriiyan jade. Oun ni irin-ise ti awon ohkowe maa ri Id lati gbe ise ona alatinuda won kale. Olabimtan (1986: 77) se afomp arifani rila ti awon bhkowe/akewi ni ti eni ti Ki i se brikowe/akewi kd ni. 0 salaye pe: Arifani naa ni agba'ra lati Io ede ni ona ti d ba wu won, ki ew'i won ba Ie se ise ti won fe ki d se. Nipa bayii, kd si ete ti won kd le fi ede pa.(o.i 77) 0 salaye' siwa'ju si i pe: Akewi ki' i se eru ede, ohun amulb ni ede fun un. Oju tiwa ni d ti yapa, ni odd tire, d Io gbdldhun bhu'n ni ona ti o' Ie gbe ero inu jade ni.
- ItemOpen AccessÀgbéyẹ̀wò Ọnà-èdè nínú àwọn Ìwé Ìtàn-Àròsọ D.O. Fágúnwà Márààrún’. Ọ̀tun Ìmọ̀ Nínú Ìtàn-Àròsọ D.O. Fágúnwà. Ẹgbẹ́ Onímọ̀ Èdè Yorùbá(Egb6 Onimd-Ede Yoruba (Yoruba Studies Association of Nigeria, 2016) Òjó, E. T.Ise ona alawbmo liti'reso je okan pataki lara ohun eld fun sise agbeyewd ona-ede. Onkowe Fagunwa nmu itan arose re maraarun je ont'se ona ti d mo bi a ti h se amulo ona-ede lati mu ki dye ohun to ri so ye eniyan yekeyeke. Tiori ifoju-ihun-wo ni irinse ti a fi se itise ati itupale lati fi wo bi Fagunwa se Io ede ninu itan aroso re maraarun. Tiori yii se afihan bi Fagunwa ti ri sa ord yan, ti d si h hun awon oro naa po. Lara awon ohun ti ise yii gbeyewo ni wiwo die lara orisiirisii ona-ede ti Fagunwa se amulo. Awon ona- ede bii Afiwe, eyi ti b pin si ona meji, Afiwe eleldo ati Afiwe taara. Bakan naa, a wo awon ona-ede miiran bii Ifbrddara, Awitunwi, Asoregee, ise ti won ri se ati ipa ti won kd ninu iwe itan aroso re. A ri ibayemu won ninu itan aroso meriiin Fagunwa ati lawujo ode bni. Arifayo ise yii ni pe ojuldwd ede Yoruba ni Fagunwa fi gbe awon itan aroso re kale; o si kun fun orisiirisii ona. Awon ona-ede yii si buyi kun ede ti Fagunwa Id. Ni ikadii, ise yii fi han pe afedesona ati onise ona alatinuda ti b dahgajia, ti d si jawe olubori ninu ise ona liti'reso ni Fagunwa.
- ItemOpen AccessIpa tí Gèlè Wíwé ńkó Nínu Oge Ṣíṣe Láwùjọ Yorùbá Lóde-Òní’. Láàńgbàsà Jọ́nà Iṣẹ́ Akadá ní Èdè Yorùbá(Department of Linguistics, African & Asian Studies, University of Lagos., 2016) Òjó, E. T.; Adébóyè, F.D.; Ọyágbénjó, D.Ohun to je lajori ninu ise yiiniagbeyewb ipa tigele wiwe n kd ninu asa oge si^e lawujg Yoruba. Sugbdn,a 6 kdkd se alaye ni soki toriohun ti iranYoruba ka kun oge sise nitoripe omi la a koko te, ka to te iyanrin Iodo. Ipa tigele wiwe n kd, irufe gele wiwe ati ami tia n fi gele se ni ydd hande ninu ise yii6 ye kia la a mole nibipe tiori Imo Hb-ami ni tiori ti6 la oju wa siawon ibi koldfin tiise b tri de Iorigele wiwe lawujo Yoruba. Sugbon, nipase tiori yii, a sakiyesi pe nnkan ki si ese ragd ni bro oge sise, a jeran tan, 6 ku eegun. 6 ni arokb ati ibanisord tia n fi gele wiwe pa laye atijd bi d tile je wi pe bkanjua n dagba, pgbon n te siwaju, iyatb ti ba iwe aarp Hana gele wiwe ati arokb ti awon obinrin Yoruba fi n pa laye atijd. A d nii saimenuba Hana iparokb naa kiise yiiIe kese jarinitoripe bi a ba ta a, d ye kia to p, bia kb ba to 6, yo6 di eran onidin ni. Idi niyi ti a fi se afihan ipa tigele wiwe h kd ninu oge sise pelu arokb tia h fi gele wiwe pa. A se afayo pe, kaka kiHe d ku, He yod se ni, kaka ki asa Yoruba d Io bkun igbagbe, ayipada ni yob ya de ba a. Ohun to tun dabi afojusun wa miiran ni sitai gele wiwe ni ibi ayeye bi: ikdmo, igbeyawd,lsiie, oku agba, oye jije ati bee bee Io. Eyi to je pe bun gan-an io maa h fi ami tab iparokb han. Asa oge sise di btun to n yo bigjb, kb parun rara gege bid se han ninu arifayo wa pe pupb ninu orin ati ipede to gbe igbagbp Yoruba yp nipa gele wiwe Id ri gbdgo fun okunrr eyiio mu kia fonrere isetdfabo ninu ise yii.
- ItemOpen AccessLinguistic Strategies of Kọ́lá Akínlàdé’s Literary Idiolect’. Inquiry(Department of Linguistics and Languages, Faculty of Arts, Adekunle Ajasin University, Akungba-Akoko, Nigeria., 2018) Òjó, E. T.This study examines linguistic strategies employed by Kola Akinlade in his detective novels, with a view to determining his literary idiolect. Halliday’s Systemic Functional Linguistics SFL) is adopted as the linguisticframework to analyze eight detective novels namely: Owo te tmddkunsikd, Agbdko Nile Tete, Albsi Qlpgo, Asenibanidaro, Ta Id gbingi Ord?, Aja to n lepa Ekun, Owo Eje, and Sahgbd Fp. The linguistic strategies extractedfor the purpose of 'his study are: coinages, code-mixing and coded language. The study establishes that coinage serves stylistic and aesthetic purposes, and enables expressions of new concepts and ideas emanating from science and technology. Furthermore, code mixing reveals Akinlade's bilingual competence, while the use ofcoded language is a mark ofAkinlade sspecial creative ability. This work specifically establishes Kola Akinlade’s individuality and personalized language style as an accomplished literary artist.
- ItemOpen AccessGraphology as a Communicative Strategy in Akínlàdé’s Detective Novels(2018) Òjó, E. T.Graphology is a communicative tool whose vast contribution to meaning-making in literary works still needs to be explored. This paper focuses on the communicative strategies employed by Kola Akinlade in his detective novels, with a view to bringing to the fore his idiosyncratic style, thereby establishing the aesthetic and communicative exploration of language. Systemic Theory; a descriptive theory which can explain any aspect of texts, be it phonological, morphological, synctactic, graphological and semantic, is adopted as the linguistic framework to analyze all the eleven detective novels of Kola Akinlade namely;Ta 16 pa Qmpoba, Owpte Amookunsika, Aldsi Olpgo, QwpEje, Aja to nlepa Ekun, Agbako NileTete, Asenibanidaro, SangbaFp, Ta Id gbingi Oro?, Ta LOleAjpmogbe, and A.slri AmookunJale Tu. Only two features of Graphology; namely capitalization and itaiicization are discussed in this paper. The study establishes that capitalization serves foregrounding and aesthetic purposes, while itaiicization provides stylistic variations, which attract readers to writers’ messages.