Àgbéyẹ̀wò Ọnà-èdè nínú àwọn Ìwé Ìtàn-Àròsọ D.O. Fágúnwà Márààrún’. Ọ̀tun Ìmọ̀ Nínú Ìtàn-Àròsọ D.O. Fágúnwà. Ẹgbẹ́ Onímọ̀ Èdè Yorùbá
dc.contributor.author | Òjó, E. T. | |
dc.date.accessioned | 2025-09-20T14:26:01Z | |
dc.date.available | 2025-09-20T14:26:01Z | |
dc.date.issued | 2016 | |
dc.description | Scholarly article | |
dc.description.abstract | Ise ona alawbmo liti'reso je okan pataki lara ohun eld fun sise agbeyewd ona-ede. Onkowe Fagunwa nmu itan arose re maraarun je ont'se ona ti d mo bi a ti h se amulo ona-ede lati mu ki dye ohun to ri so ye eniyan yekeyeke. Tiori ifoju-ihun-wo ni irinse ti a fi se itise ati itupale lati fi wo bi Fagunwa se Io ede ninu itan aroso re maraarun. Tiori yii se afihan bi Fagunwa ti ri sa ord yan, ti d si h hun awon oro naa po. Lara awon ohun ti ise yii gbeyewo ni wiwo die lara orisiirisii ona-ede ti Fagunwa se amulo. Awon ona- ede bii Afiwe, eyi ti b pin si ona meji, Afiwe eleldo ati Afiwe taara. Bakan naa, a wo awon ona-ede miiran bii Ifbrddara, Awitunwi, Asoregee, ise ti won ri se ati ipa ti won kd ninu iwe itan aroso re. A ri ibayemu won ninu itan aroso meriiin Fagunwa ati lawujo ode bni. Arifayo ise yii ni pe ojuldwd ede Yoruba ni Fagunwa fi gbe awon itan aroso re kale; o si kun fun orisiirisii ona. Awon ona-ede yii si buyi kun ede ti Fagunwa Id. Ni ikadii, ise yii fi han pe afedesona ati onise ona alatinuda ti b dahgajia, ti d si jawe olubori ninu ise ona liti'reso ni Fagunwa. | |
dc.identifier.citation | Òjó, E. T. (2016) ‘Àgbéyẹ̀wò Ọnà-èdè nínú àwọn Ìwé Ìtàn-Àròsọ D.O. Fágúnwà Márààrún’. Ọ̀tun Ìmọ̀ Nínú Ìtàn-Àròsọ D.O. Fágúnwà. Ẹgbẹ́ Onímọ̀ Èdè Yorùbá. – Yoruba Studies Association of Nigeria. 296-309. | |
dc.identifier.isbn | 978-34934 - 9 - 3 | |
dc.identifier.uri | https://ir.unilag.edu.ng/handle/123456789/13406 | |
dc.language.iso | yo | |
dc.publisher | Egb6 Onimd-Ede Yoruba (Yoruba Studies Association of Nigeria | |
dc.title | Àgbéyẹ̀wò Ọnà-èdè nínú àwọn Ìwé Ìtàn-Àròsọ D.O. Fágúnwà Márààrún’. Ọ̀tun Ìmọ̀ Nínú Ìtàn-Àròsọ D.O. Fágúnwà. Ẹgbẹ́ Onímọ̀ Èdè Yorùbá | |
dc.type | Book chapter |