Ìbà: Èròjà Kò-ṣeé-mọ́-nì-ín fún Lítíréṣọ̀ Alohùn Yorùbá
No Thumbnail Available
Date
2015-06-05
Authors
Orimoogunje, O.C
Journal Title
Journal ISSN
Volume Title
Publisher
A Publication of the Department of Linguistics and Nigerian Languages, Adékúnlé Ajásin University, Àkùngbá
Abstract
Yorùbá bọ̀ wón ní a kì í ṣòòṣà lódò kí làbẹlàbẹ má mọ̀, bẹ́ẹ̀ gan-an ni ọ̀rọ̀ ìjúbà rí nínú Lítíréṣọ̀ alohùn Yorùbá. Ìdí ni pé kò sí agbátẹrù Lítíréṣọ̀ alohùn tí kò ní fi ti ìbà ṣáájú ohun gbogbo. Láìjẹ́ bẹ́ẹ̀, ìgbàgbọ́ wọn ni pé, ọ̀bẹ àwọn alayé yóò bá a.