Ihun Awon Iso Elerun-Un Ni Yoruba

dc.contributor.authorIlori, J.F
dc.date.accessioned2017-10-19T14:29:43Z
dc.date.available2017-10-19T14:29:43Z
dc.date.issued2015
dc.descriptionStaff Publicationen_US
dc.description.abstractAlaye itupale ihun awon iso elerun-un ni, paapaa ehun [OR ni OR] (to wa ninu gbolohun bf Akin pa [mama ni eran), ati ise ti ni n se nibe ko tii niyanju ninu glrama Yoruba (Awobuluyl 1978, 2013; Oyelaran 1989; Bamgbose 1990). Beba yii pe akiyesi si awon eri tuntun kan nipa ehun semantiikl ati sintaasl awon iso naa eyi to fi ro arojare pe ete itenumo onni (possessor) yato si ini (possessum) inu ehun onibaatan to je ipile ti a ti seda iso elerun-un-ni onibaatan-ajemo-ini (possessive-genitive ni-expression) lo bi idaru aato inu ihun awon isoyen. Bakan naa lo tun gbe eri kale lati fi han pe wunren ni kan yii naa lo n jeyo ninu awori iso ti a ti maa n sope ni n sise oro-atokun to n toka ibi/ogangan-isele (location) ninu girama Yoruba.en_US
dc.identifier.citationIlori,J.F. (2015) Ihun Awon Iso Elerun-Un Ni Yoruba. LAANGBASA (Jona Ise Akada Ni Ede Yoruba), (19),p. 125 - 145.en_US
dc.identifier.issn0794 - 3881
dc.identifier.urihttp://ir.unilag.edu.ng:8080/xmlui/handle/123456789/2416
dc.language.isootheren_US
dc.relation.ispartofseriesStaff Publication;
dc.subjectSemantiikien_US
dc.subjectSintaasien_US
dc.titleIhun Awon Iso Elerun-Un Ni Yorubaen_US
dc.typeArticleen_US
Files
Original bundle
Now showing 1 - 1 of 1
Loading...
Thumbnail Image
Name:
LAANGBASA [JONA ISE AKADA NI EDE YORUBA] ISSN 0794 -3881 NONBA 19 ODUN.pdf
Size:
19.68 MB
Format:
Adobe Portable Document Format
Description:
Full Text
License bundle
Now showing 1 - 1 of 1
Loading...
Thumbnail Image
Name:
license.txt
Size:
1.71 KB
Format:
Item-specific license agreed upon to submission
Description: