Linguistics-Scholarly Publications
Permanent URI for this collection
Browse
Browsing Linguistics-Scholarly Publications by Subject "Alopo"
Now showing 1 - 1 of 1
Results Per Page
Sort Options
- ItemOpen AccessItopinpin Atoka Iseweku Ajemotumo Alopo Ninu Asayan Afo Yoruba(2015) Okewande, O.T.lseweku afo ni i se pelu oro-alopo; paapaa, pelu oro-ise ati oro oruko iru afo bee. Lilo alopo to ni isopo iseweku pelu iru oro bee ni yoo safihan ikogoja imede.Pup awon alopo itumo ajemoro-ise ati oro-oruko lo ti di isinipopada kuro ni ilana isenbaye (onide); sugbon, ti a n se ifiropo, pasipaaro tabi idaro itumo fun ninu afo. Ijeyo iru awon alopo wonyi ni a topinpin lati inu awon afo Yoruba to je oro-oruko ponbele, ofo, akanlo-ede, oriki ati owe. lgbede ati imede ni i seni i se pelu isamulo imo imedelo oro to ni itumo alopo iseweku. Ijeyo orisun ilana isenbaye maa n jeyo peu eranko, igi, kokoro. ohun abemi ati alailemii. A pin ilana itumo oro-ede fayewo si merin: atoka ajemotumo alopo iseweku onide ninu afo, atoka ajemotumo(J11II119ifonka-aseyato aloptj iseweku ninu afo, atoka ajemotumo ifonka aseyato alopo iseweku nlnu afo ati atoka ajemotumo ifonka aseyato alopo iseweku onibaatan ninu afo. A topinpin orisun ijeyoa awon afo ti a samulo fun itupale bi won ti se jeyo pelu oro oruko tabi apola oruko ni alopo pelu oro-ise lati isenbaye ninu afo: owe,afiwe, oriki ati ofo. Abajade iwadii yii fihan pe pupo itumo re maa nkun bee si nio maa n ni imolara ipa itumo ara oto Lona miiran ewe, ipegede itumo ipele ijeyo afo ifonka-aseyato, ifonka-alaiseyato ati afo onitumo ibatan da lorl idogba ati iseweku alopo itumo afo pelu onide. Amulo alopo iseweku ajemotumo lo nfi imede han ninu imo imedelo.