Itopinpin Atoka Iseweku Ajemotumo Alopo Ninu Asayan Afo Yoruba

Loading...
Thumbnail Image
Date
2015
Authors
Okewande, O.T.
Journal Title
Journal ISSN
Volume Title
Publisher
Abstract
lseweku afo ni i se pelu oro-alopo; paapaa, pelu oro-ise ati oro oruko iru afo bee. Lilo alopo to ni isopo iseweku pelu iru oro bee ni yoo safihan ikogoja imede.Pup awon alopo itumo ajemoro-ise ati oro-oruko lo ti di isinipopada kuro ni ilana isenbaye (onide); sugbon, ti a n se ifiropo, pasipaaro tabi idaro itumo fun ninu afo. Ijeyo iru awon alopo wonyi ni a topinpin lati inu awon afo Yoruba to je oro-oruko ponbele, ofo, akanlo-ede, oriki ati owe. lgbede ati imede ni i seni i se pelu isamulo imo imedelo oro to ni itumo alopo iseweku. Ijeyo orisun ilana isenbaye maa n jeyo peu eranko, igi, kokoro. ohun abemi ati alailemii. A pin ilana itumo oro-ede fayewo si merin: atoka ajemotumo alopo iseweku onide ninu afo, atoka ajemotumo(J11II119ifonka-aseyato aloptj iseweku ninu afo, atoka ajemotumo ifonka aseyato alopo iseweku nlnu afo ati atoka ajemotumo ifonka aseyato alopo iseweku onibaatan ninu afo. A topinpin orisun ijeyoa awon afo ti a samulo fun itupale bi won ti se jeyo pelu oro oruko tabi apola oruko ni alopo pelu oro-ise lati isenbaye ninu afo: owe,afiwe, oriki ati ofo. Abajade iwadii yii fihan pe pupo itumo re maa nkun bee si nio maa n ni imolara ipa itumo ara oto Lona miiran ewe, ipegede itumo ipele ijeyo afo ifonka-aseyato, ifonka-alaiseyato ati afo onitumo ibatan da lorl idogba ati iseweku alopo itumo afo pelu onide. Amulo alopo iseweku ajemotumo lo nfi imede han ninu imo imedelo.
Description
Staff Publication
Keywords
Iseweku , Alopo
Citation
Okewande,O.T. (2015) Itopinpin Atoka Iseweku Ajemotumo Alopo Ninu Asayan Afo Yoruba. Eka-Eko lmo-Eda-Ede ati Awon Ede-orile-ede Naijirla, Yunifasiti llorin, llorin. (19), p. 1 - 20.