Itopinpin Atoka Iseweku Ajemotumo Alopo Ninu Asayan Afo Yoruba

dc.contributor.authorOkewande, O.T.
dc.date.accessioned2017-10-19T13:28:40Z
dc.date.available2017-10-19T13:28:40Z
dc.date.issued2015
dc.descriptionStaff Publicationen_US
dc.description.abstractlseweku afo ni i se pelu oro-alopo; paapaa, pelu oro-ise ati oro oruko iru afo bee. Lilo alopo to ni isopo iseweku pelu iru oro bee ni yoo safihan ikogoja imede.Pup awon alopo itumo ajemoro-ise ati oro-oruko lo ti di isinipopada kuro ni ilana isenbaye (onide); sugbon, ti a n se ifiropo, pasipaaro tabi idaro itumo fun ninu afo. Ijeyo iru awon alopo wonyi ni a topinpin lati inu awon afo Yoruba to je oro-oruko ponbele, ofo, akanlo-ede, oriki ati owe. lgbede ati imede ni i seni i se pelu isamulo imo imedelo oro to ni itumo alopo iseweku. Ijeyo orisun ilana isenbaye maa n jeyo peu eranko, igi, kokoro. ohun abemi ati alailemii. A pin ilana itumo oro-ede fayewo si merin: atoka ajemotumo alopo iseweku onide ninu afo, atoka ajemotumo(J11II119ifonka-aseyato aloptj iseweku ninu afo, atoka ajemotumo ifonka aseyato alopo iseweku nlnu afo ati atoka ajemotumo ifonka aseyato alopo iseweku onibaatan ninu afo. A topinpin orisun ijeyoa awon afo ti a samulo fun itupale bi won ti se jeyo pelu oro oruko tabi apola oruko ni alopo pelu oro-ise lati isenbaye ninu afo: owe,afiwe, oriki ati ofo. Abajade iwadii yii fihan pe pupo itumo re maa nkun bee si nio maa n ni imolara ipa itumo ara oto Lona miiran ewe, ipegede itumo ipele ijeyo afo ifonka-aseyato, ifonka-alaiseyato ati afo onitumo ibatan da lorl idogba ati iseweku alopo itumo afo pelu onide. Amulo alopo iseweku ajemotumo lo nfi imede han ninu imo imedelo.en_US
dc.identifier.citationOkewande,O.T. (2015) Itopinpin Atoka Iseweku Ajemotumo Alopo Ninu Asayan Afo Yoruba. Eka-Eko lmo-Eda-Ede ati Awon Ede-orile-ede Naijirla, Yunifasiti llorin, llorin. (19), p. 1 - 20.en_US
dc.identifier.issn0794 - 3881
dc.identifier.urihttp://ir.unilag.edu.ng:8080/xmlui/handle/123456789/2414
dc.language.isoenen_US
dc.relation.ispartofseriesStaff Publication;
dc.subjectIsewekuen_US
dc.subjectAlopoen_US
dc.titleItopinpin Atoka Iseweku Ajemotumo Alopo Ninu Asayan Afo Yorubaen_US
dc.typeArticleen_US
Files
Original bundle
Now showing 1 - 1 of 1
Loading...
Thumbnail Image
Name:
LAANGBASA [JONA ISE AKADA NI EDE YORUBA] ISSN 0794 -3881 NONBA 19 ODUN.pdf
Size:
19.68 MB
Format:
Adobe Portable Document Format
Description:
Full Text
License bundle
Now showing 1 - 1 of 1
Loading...
Thumbnail Image
Name:
license.txt
Size:
1.71 KB
Format:
Item-specific license agreed upon to submission
Description: