Ihun Ati Itumo Oruka Aseda Yoruba Nipa Afomo Ibeere.

dc.contributor.authorEleshin, B.
dc.date.accessioned2017-10-19T14:11:45Z
dc.date.available2017-10-19T14:11:45Z
dc.date.issued2015
dc.descriptionStaff Publicationen_US
dc.description.abstractIseda oruko ni awujo Yoruba pin si orisirisi ona. Lara won ni ilo afomo ibere, isogbolohun di oruko, alopo oro-oruko meji ati bee bee Io. Orisii afomo mejl lo wa ninu ede Yoruba; afomo ibere ati afomo asopo. Ninu awon mejeeji yi, aforno ibere nikan ni a mo ti o le kepa ninu iseda oruko. Marun-un ni awon afomo lbere ti a samulo ninu pepa yil. Itumo awon afomo yii le, yala je "omo tl o...tabi "omo ti a ...". Awon afomo ibere kan ni itumo mejeeji yii,bee awon kan ko ni ju itumo kan Io.Ni ti ihun, a ri pe ihun awon oruko ti a seda pelu afomo ibere yato si awon ti a seda nipase llana miiran. A tubo safihan iyato laarin ihun awon oruko bayi nipa ilo Aba ipile labe Tiori Onipele Aba ipile fun Apola safihan ti a o lo ni pato ni eyl to wa ni ibamu peIu alaye Aboh (1999) lori tiori aMulo naa. Ohun to gun wa ni kese lati dawo le ise yii ni:(1) Lati fi iyato han laarin ihun awon oruko ti a seda nipa afomo lbere ati awon tl a seda nipase ona miiran nipa IBo Aba ipile fun Apola Asafihan (DP Hypothesis). (2) Lati satunyewo ltumo ti awon afomo lbere maa n ni ninu iseda oruko.en_US
dc.identifier.citationEleshin,B. (Ihun Ati Itumo Oruka Aseda Yoruba Nipa Afomo Ibeere.LANGBASA (Jona Ise Akada Ni Ede Yoruba). Department of Linguistics, African and Asian Studies, University of Lagos, (19), p. 21 - 36.en_US
dc.identifier.issn0794 - 3881
dc.identifier.urihttp://ir.unilag.edu.ng:8080/xmlui/handle/123456789/2415
dc.language.isootheren_US
dc.relation.ispartofseriesStaff Publication;
dc.subjectAfomoen_US
dc.subjectAfomo ibereen_US
dc.titleIhun Ati Itumo Oruka Aseda Yoruba Nipa Afomo Ibeere.en_US
dc.typeArticleen_US
Files
Original bundle
Now showing 1 - 1 of 1
Loading...
Thumbnail Image
Name:
LAANGBASA [JONA ISE AKADA NI EDE YORUBA] ISSN 0794 -3881 NONBA 19 ODUN.pdf
Size:
19.68 MB
Format:
Adobe Portable Document Format
Description:
Full Text
License bundle
Now showing 1 - 1 of 1
Loading...
Thumbnail Image
Name:
license.txt
Size:
1.71 KB
Format:
Item-specific license agreed upon to submission
Description: