Oní/Oni kì í Ṣe Móf̣ íìmù Kan Nínú Gírámà Yorùbá
No Thumbnail Available
Date
2011
Authors
Ilọri, J.F.
Journal Title
Journal ISSN
Volume Title
Publisher
Adekunle Ajasin University, Akungba-Akoko
Abstract
Ìfáárà
Nínú gírámà Yorùbá, àfòmó ̣ ìbèṛ è ̣ tí kò ṣe é pín ni ò ̣pòḷ ọpò ̣ ka oni àti oní sí. Bámgbóṣé (1990:104) fi èrò yìí múlè ̣nígbà tí wó ̣n sọ pé èdè Yorùbá máa ń fi àfòmó ̣ ìbèṛ è ̣oni- kún OR láti ṣe ìsọdorúkọ olùṣe tí a fi máa ń ró ̣pò APOR: ẹni tó ṣe nǹkan. Lára àpẹẹrẹ tí wó ̣n fi gbe àlàyé náà lé ̣sè ̣ni (1)1.
1a. oni- ùbè ̣wò olùbè ̣wò
b. oni- ùgbèjà olùgbèjà
Ní ti oní, Bámgbóṣé (1990:107) ṣàlàyé pé ìsọdorúkọ ìní ni Yorùbá ń lò ó fún àtipé ìtumò ̣ẹni tí ó ni nǹkan ló máa ń gbé jáde, b.a. (2).
2a. oní- aṣọ aláṣọ (ẹni tó ni aṣọ tàbí tí ó ń ta aṣo)
b. oní- ogun ológun (ẹni tí ó ni ogun tàbí tí ó ń ja ogun)
Ìbéèrè tó wá síni ló ̣kàn ló ̣gangan yìí ni pé ṣé òótó ̣ ni oni àti oní kò ṣe é fó ̣ sí
wé ̣wé ̣ pàápàá bí a bá fojú ìtumò ̣ tí wó ̣n sọ pé wó ̣n ń gbé jáde ní (1) àti (2) wo ìhun
wọn? Èròǹgbà wa nínú bébà yìí ni láti fi hàn pé èṛ í inú Yorùbá àjùmòḷ ò àti tàwọn
è ̣ka-èdè rè ̣ kò gbe èrò àbáláyé yìí lé ̣sè ̣ àtipé mó ̣fíìmù méjì-méjì ló wà nínú àwọn
wúnrè ̣n wò ̣nyẹn.
Description
Scholarly article
Keywords
Citation
Ilori, J. F. 2011. ‘Oní/Oni kì í Ṣe Mọ́fíìmù Kan nínú Gírámà Yorùbá (Oní/Oni is not an indivisible Morpheme in Yoruba Grammar). Akungba Journal of Linguistics and Literatures, No 2, pages 12-17.Adekunle Ajasin University, Akungba-Akoko.