Oní/Oni kì í Ṣe Móf̣ íìmù Kan Nínú Gírámà Yorùbá
dc.contributor.author | Ilọri, J.F. | |
dc.date.accessioned | 2022-12-13T14:50:44Z | |
dc.date.available | 2022-12-13T14:50:44Z | |
dc.date.issued | 2011 | |
dc.description | Scholarly article | |
dc.description.abstract | Ìfáárà Nínú gírámà Yorùbá, àfòmó ̣ ìbèṛ è ̣ tí kò ṣe é pín ni ò ̣pòḷ ọpò ̣ ka oni àti oní sí. Bámgbóṣé (1990:104) fi èrò yìí múlè ̣nígbà tí wó ̣n sọ pé èdè Yorùbá máa ń fi àfòmó ̣ ìbèṛ è ̣oni- kún OR láti ṣe ìsọdorúkọ olùṣe tí a fi máa ń ró ̣pò APOR: ẹni tó ṣe nǹkan. Lára àpẹẹrẹ tí wó ̣n fi gbe àlàyé náà lé ̣sè ̣ni (1)1. 1a. oni- ùbè ̣wò olùbè ̣wò b. oni- ùgbèjà olùgbèjà Ní ti oní, Bámgbóṣé (1990:107) ṣàlàyé pé ìsọdorúkọ ìní ni Yorùbá ń lò ó fún àtipé ìtumò ̣ẹni tí ó ni nǹkan ló máa ń gbé jáde, b.a. (2). 2a. oní- aṣọ aláṣọ (ẹni tó ni aṣọ tàbí tí ó ń ta aṣo) b. oní- ogun ológun (ẹni tí ó ni ogun tàbí tí ó ń ja ogun) Ìbéèrè tó wá síni ló ̣kàn ló ̣gangan yìí ni pé ṣé òótó ̣ ni oni àti oní kò ṣe é fó ̣ sí wé ̣wé ̣ pàápàá bí a bá fojú ìtumò ̣ tí wó ̣n sọ pé wó ̣n ń gbé jáde ní (1) àti (2) wo ìhun wọn? Èròǹgbà wa nínú bébà yìí ni láti fi hàn pé èṛ í inú Yorùbá àjùmòḷ ò àti tàwọn è ̣ka-èdè rè ̣ kò gbe èrò àbáláyé yìí lé ̣sè ̣ àtipé mó ̣fíìmù méjì-méjì ló wà nínú àwọn wúnrè ̣n wò ̣nyẹn. | |
dc.identifier.citation | Ilori, J. F. 2011. ‘Oní/Oni kì í Ṣe Mọ́fíìmù Kan nínú Gírámà Yorùbá (Oní/Oni is not an indivisible Morpheme in Yoruba Grammar). Akungba Journal of Linguistics and Literatures, No 2, pages 12-17.Adekunle Ajasin University, Akungba-Akoko. | |
dc.identifier.uri | https://ir.unilag.edu.ng/handle/123456789/11954 | |
dc.publisher | Adekunle Ajasin University, Akungba-Akoko | |
dc.relation.ispartofseries | Akungba Journal of Linguistics and Literatures; 2 | |
dc.title | Oní/Oni kì í Ṣe Móf̣ íìmù Kan Nínú Gírámà Yorùbá | |
dc.type | Article |